àwọn ẹ̀tọ́ rẹ
Fún ìgbádùn apu yi, tẹ ìkan nínú àwọn ẹ̀tọ́ rẹ wọ̀nyí:
- Bí ènìyàn se lè jẹ́ ọmọ Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi láti ní oun ìní
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi fún òmìnira lòdì sí ìyàsọ́tọ̀ ìkórìra
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi fún òmìnira láti rìn káàkiri
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi láti kórajọ ní àlàfíà àti láti bá ènìyàn kẹ́gbẹ́ pọ̀
- ẹ̀tọ́ọ̀ òmìnira mi láti sọ àti ti ìròhìn
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi fún òmìnira èrò, ọkàn àti ẹ̀sìn
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi si ìpamọ́n
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi fún gbígbọ̀ tẹnu mìi láìsí ojùsàájú
- ẹ̀tọ́ tó fún mi ní òmìnira
- ẹ̀tọ́ọ̀ mi láti wà láyé