Entries by KnowYourRightsNigeria

ẹ̀tọ́ọ̀ mi láti wà láyé

(1) Gbogbo ènìyàn lóní ẹ̀tọ́ láti wà láyé àti wí pé kòsí ẹni tó gbọ́dọ̀ gba ẹ̀mí enikejì àyàfi tí ẹni náà bá gba ìdajọ́ ikú fún ìwà búburú tó lòdì sí òfin, tí ilé ẹjọ́ sì ri wí pé ó jẹ̀bi ẹ̀sùn náà. (2) ẹni tó bá fi ipá kọlu ẹni kejì tí wọ́n […]